1 Ọba 4:25 BMY

25 Nígbà ayé Sólómónì, Júdà àti Ísírẹ́lì, láti Dánì títí dé Béríṣébà, wọ́n ń gbé ní àlàáfíà, olúkúlùkù lábẹ́ àjàrà rẹ̀ àti lábẹ́ igi ọ̀pọ̀tọ́ rẹ̀.

Ka pipe ipin 1 Ọba 4

Wo 1 Ọba 4:25 ni o tọ