1 Ọba 4:33 BMY

33 Ó sì sọ̀rọ̀ ti igi, láti Kédárì tí ń bẹ ní Lébánónì dé Hísópù tí ń dàgbà lára ògiri. Ó sì tún sọ ti àwọn ẹranko àti ti àwọn ẹyẹ, àti ohun tí ń rákò àti ti ẹja.

Ka pipe ipin 1 Ọba 4

Wo 1 Ọba 4:33 ni o tọ