1 Ọba 5:13 BMY

13 Sólómónì ọba sì sa asìnrú ènìyàn jọ ní gbogbo Ísírẹ́lì; àwọn tí ń sìnrú náà jẹ́ ẹgbàá mẹ́ẹ̀dógún ènìyàn (30,000).

Ka pipe ipin 1 Ọba 5

Wo 1 Ọba 5:13 ni o tọ