1 Ọba 5:18 BMY

18 Àwọn oníṣọ̀nà Sólómónì àti Hírámù àti àwọn ènìyàn Gébálì sì gbẹ́ wọn, wọ́n sì pèsè igi àti òkúta láti fi kọ́ ilé náà.

Ka pipe ipin 1 Ọba 5

Wo 1 Ọba 5:18 ni o tọ