1 Ọba 5:4 BMY

4 Ṣùgbọ́n nísinsìn yìí Olúwa Ọlọ́run mi ti fún mi ní ìsinmi ní ibi gbogbo, bẹ́ẹ̀ ni kò sì sí ọ̀tá tàbí ìjàǹbá kan tí ó ṣe.

Ka pipe ipin 1 Ọba 5

Wo 1 Ọba 5:4 ni o tọ