1 Ọba 7:45 BMY

45 Ìkòkò, ọkọ́ àti àwo kòtò.Gbogbo ohun èlò wọ̀nyí tí Hírámù ṣe fún Sólómónì ọba nítorí iṣẹ́ Olúwa sì jẹ́ idẹ dídán.

Ka pipe ipin 1 Ọba 7

Wo 1 Ọba 7:45 ni o tọ