1 Ọba 8:8 BMY

8 Àwọn ọ̀pá yìí ga tó bẹ́ẹ̀ tí a fi le rí orí wọn láti ibi mímọ́ níwájú ibi tí a yà sí mímọ́, ṣùgbọ́n a kò sì rí wọn lóde ibi mímọ́, wọ́n sì wà níbẹ̀ títí di òní yìí.

Ka pipe ipin 1 Ọba 8

Wo 1 Ọba 8:8 ni o tọ