1 Ọba 9:1 BMY

1 Nígbà tí Solómónì sì parí kíkọ́ ilé Olúwa àti ààfin ọba, tí ó sì ti ṣe gbogbo nǹkan tí ó ń fẹ́ láti ṣe,

Ka pipe ipin 1 Ọba 9

Wo 1 Ọba 9:1 ni o tọ