1 Ọba 9:21 BMY

21 ìyẹn ni pé àwọn ọmọ wọn tí ó kù ní ilẹ̀ náà, tí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì kò le parun pátapáta, àwọn ni Sólómónì bu iṣẹ́ ìrú fún títí di òní yìí.

Ka pipe ipin 1 Ọba 9

Wo 1 Ọba 9:21 ni o tọ