24 Lẹ́yìn ìgbà tí ọmọbìnrin Fáráò ti gòkè láti ìlú Dáfídì wá sí ààfin tí Sólómónì kọ́ fún un, nígbà náà ni ó kọ́ Mílò.
Ka pipe ipin 1 Ọba 9
Wo 1 Ọba 9:24 ni o tọ