2 Ọba 10:22 BMY

22 Jéhù sì sọ fún olùṣọ́ pé, “Kí ó mú aṣọ ìgúnwà wá fún gbogbo àwọn òjíṣẹ́ Báálì.” Bẹ́ẹ̀ ni ó mú aṣọ ìgúnwà jáde wá fún wọn.

Ka pipe ipin 2 Ọba 10

Wo 2 Ọba 10:22 ni o tọ