2 Ọba 10:29 BMY

29 Bí ó ti wù kí ó rí, kò yípadà kúrò nínú ẹ̀ṣẹ̀ Jéróbóámù ọmọ Nébátì, tí ó ṣokùnfà Ísírẹ́lì láti dá—ti sísin ẹgbọ̀rọ̀ màlúù wúrà ní Bétélì àti Dánì.

Ka pipe ipin 2 Ọba 10

Wo 2 Ọba 10:29 ni o tọ