2 Ọba 12:16 BMY

16 Owó láti ibi ọrẹ ẹ̀bi àti ọrẹ ẹ̀ṣẹ̀ ní a kò mú wá sí ilé tí a kọ́ fún Olúwa: ó jẹ́ ti àwọn àlùfáà.

Ka pipe ipin 2 Ọba 12

Wo 2 Ọba 12:16 ni o tọ