2 Ọba 12:19 BMY

19 Pẹ̀lú ìyókù ìṣe Jóásì, àti ohun gbogbo tí ó ṣe, a kò ha kọ wọ́n sínú ìwé ìtàn ayé àwọn ọba Júdà?

Ka pipe ipin 2 Ọba 12

Wo 2 Ọba 12:19 ni o tọ