2 Ọba 12:8 BMY

8 Àwọn àlùfáà faramọ́ pé wọn kò ní gba owó kankan mọ́ lọ́wọ́ àwọn ènìyàn bẹ́ẹ̀ sì ni, wọn kò sì ní tún ilé tí a kọ́ fún Olúwa ṣe mọ́ fún ra wọn.

Ka pipe ipin 2 Ọba 12

Wo 2 Ọba 12:8 ni o tọ