2 Ọba 13:1 BMY

1 Ní ọdún kẹtàlélógún ti Jóásì ọmọ ọba Áhásáyà ti Júdà, Jéhóáhásì ọmọ Jéhù di ọba Ísírẹ́lì ní Ṣamáríà. Ó sì jọba fún ọdún mẹ́tadínlógún.

Ka pipe ipin 2 Ọba 13

Wo 2 Ọba 13:1 ni o tọ