2 Ọba 13:18 BMY

18 Nígbà náà ó wí pé, “Mú àwọn ọfà náà,” ọba sì mú wọn. Èlíṣà wí fún un pé, “Lu ilẹ̀.” Ó lù ú lẹ́ẹ̀mẹ́ta, ó sì dáwọ́ dúró.

Ka pipe ipin 2 Ọba 13

Wo 2 Ọba 13:18 ni o tọ