2 Ọba 13:4 BMY

4 Nígbà náà Jéhóáhásì kígbe ó wá ojú rere Olúwa, Olúwa sì tẹ́tí sí i. Nítorí ó rí bí ọba Ṣíríà ti ń ni Ísírẹ́lì lára gidigidi.

Ka pipe ipin 2 Ọba 13

Wo 2 Ọba 13:4 ni o tọ