2 Ọba 13:9 BMY

9 Jéhóáhásì sinmi pẹ̀lú àwọn baba rẹ̀. A sì sin ín sí Samáríà, Jéhóásì ọmọ rẹ̀ sì rọ́pọ̀ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ọba.

Ka pipe ipin 2 Ọba 13

Wo 2 Ọba 13:9 ni o tọ