2 Ọba 14:14 BMY

14 Ó mú gbogbo wúrà àti fàdákà àti gbogbo ohun tí ó rí nínú ilé tí a kọ́ fún Olúwa àti níbi ìfowópamọ́ sí nínú ààfin ọba. Ó mú àwọn ìdógò, ó sì dá wọn padà sí Ṣamáríà.

Ka pipe ipin 2 Ọba 14

Wo 2 Ọba 14:14 ni o tọ