2 Ọba 14:3 BMY

3 Ó ṣe ohun tí ó tọ́ ní ojú Olúwa, ṣùgbọ́n kì í ṣe bí i Dáfídì baba a rẹ̀ tí ṣe. Nínú ohun gbogbo, ó tẹ́lé àpẹrẹ baba a rẹ̀ Jóásì.

Ka pipe ipin 2 Ọba 14

Wo 2 Ọba 14:3 ni o tọ