2 Ọba 14:8 BMY

8 Nígbà náà, Ámásáyà rán àwọn ìránṣẹ́ sí Jóásì ọmọ Jéhóáhásì ọmọ Jéhù ọba Ísírẹ́lì pẹ̀lú ìpèlẹ́jọ́ “Wá, í bá mi lójúkorojú.”

Ka pipe ipin 2 Ọba 14

Wo 2 Ọba 14:8 ni o tọ