2 Ọba 15:1 BMY

1 Ní ọdún kẹtàdínlọ́gbọ̀n tí Jéróbóámù ọba Ísírẹ́lì, Ásáríyà ọmọ Ámásáyà ọba Júdà sì bẹ̀rẹ̀ sí ní jọba.

Ka pipe ipin 2 Ọba 15

Wo 2 Ọba 15:1 ni o tọ