2 Ọba 15:17 BMY

17 Ní ọdún kọkàndínlógójì ti Ásáríyà ọba Júdà, Ménáhémù ọmọ Gádì di ọba Ísírẹ́lì, ó sì jọba ní Samáríà fún ọdún mẹ́wàá.

Ka pipe ipin 2 Ọba 15

Wo 2 Ọba 15:17 ni o tọ