2 Ọba 15:23 BMY

23 Ní ọdún kẹẹ̀dógún Ásáríyà ọba Júdà, Pékáhíà ọmọ Ménáhémù di ọba Ísírẹ́lì ní Ṣamáríà, ó sì jọba fún ọdún méjì.

Ka pipe ipin 2 Ọba 15

Wo 2 Ọba 15:23 ni o tọ