2 Ọba 15:36 BMY

36 Fún ti ìyókù iṣẹ́ nígbà ìjọba Jótamù, àti ohun tí ó ṣe, ṣé a kò kọ wọ́n sínú ìwé ìtàn ayé àwọn ọba Júdà?

Ka pipe ipin 2 Ọba 15

Wo 2 Ọba 15:36 ni o tọ