2 Ọba 15:6 BMY

6 Fún ti ìyókù iṣẹ́ nígbà ìjọba Ásáríyà, pẹ̀lú gbogbo ohun tí ó ṣe, ṣé a kò kọ wọ́n sínú ìwé ìtàn ayé àwọn ọba Júdà.

Ka pipe ipin 2 Ọba 15

Wo 2 Ọba 15:6 ni o tọ