2 Ọba 16:18 BMY

18 Ibi ààbò fún ọjọ́ ìsinmi tí a kọ́ nínú ilé náà, àti ọ̀nà ìjáde sí òde ọba, ni ó yípadà kúrò ní ilé Olúwa nítorí ọba Ásíríà.

Ka pipe ipin 2 Ọba 16

Wo 2 Ọba 16:18 ni o tọ