2 Ọba 16:9 BMY

9 Ọba Ásíríà sì gbọ́ tirẹ̀: nítórí ọba Ásíríà gòkè wá sí Dámásíkù, ó sì kó o, ó sì mú un ní ìgbékùn lọ sí Kírì, ó sì pa Résínì.

Ka pipe ipin 2 Ọba 16

Wo 2 Ọba 16:9 ni o tọ