2 Ọba 17:17 BMY

17 Wọ́n sì fi àwọn ọmọkùnrin àti àwọn ọmọbìnrin wọn rúbọ nínú iná. Wọ́n sì n fọ̀ àfọ̀sẹ, wọ́n sì ń ṣe àlùpàyídà wọ́n sì ta ara wọn láti ṣe ohun búburú níwájú Olúwa, wọ́n sì mú-un bínú.

Ka pipe ipin 2 Ọba 17

Wo 2 Ọba 17:17 ni o tọ