2 Ọba 17:24 BMY

24 Ọba Ásíríà mú àwọn ènìyàn láti Bábílónì, Kútà, Áfà, Hámátì àti Ṣéfáfáímù wọ́n sì dúró ní ìlú Ṣamáríà láti rọ́pò àwọn ará Ísírẹ́lì. Wọ́n sì ń gbé ní ìlú náà.

Ka pipe ipin 2 Ọba 17

Wo 2 Ọba 17:24 ni o tọ