2 Ọba 17:35 BMY

35 Nígbà tí Olúwa ṣe májẹ̀mú pẹ̀lú àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ó pàṣẹ fún wọn pé: “Ẹ má ṣe sin òrìṣà mìíràn tàbí tẹríba fún wọn, sìn wọ́n tàbí kí ẹ rúbọ sí wọn.

Ka pipe ipin 2 Ọba 17

Wo 2 Ọba 17:35 ni o tọ