2 Ọba 19:12 BMY

12 Ṣé àwọn òrìṣà orílẹ̀ èdè tí a ti parun láti ọ̀dọ̀ àwọn babańlá mi gbà wọ́n là: òrìṣà Gósánì, Háránì Réṣéfù àti gbogbo ènìyàn Édẹ́nì tí wọ́n wà ní Télásárì?

Ka pipe ipin 2 Ọba 19

Wo 2 Ọba 19:12 ni o tọ