2 Ọba 19:8 BMY

8 Nígbà tí olùdarí pápá gbọ́ wí pé ọba Áṣíríà ti kúrò lákìsì ó sì padà ó sì rí ọba níbi ti ó gbé ń bá Líbíńà jà.

Ka pipe ipin 2 Ọba 19

Wo 2 Ọba 19:8 ni o tọ