2 Ọba 2:24 BMY

24 Ó sì yípadà, ó sì wò wọ́n ó sì fi wọ́n bú ní orúkọ Olúwa. Nígbà náà béárì méjì sì jáde wá láti inú igbó ó sì lu méjìlélógójì (42) lára àwọn ọ̀dọ́ náà.

Ka pipe ipin 2 Ọba 2

Wo 2 Ọba 2:24 ni o tọ