2 Ọba 21:17 BMY

17 Ní ti iṣẹ́ ìyókù ti ìjọba Mánásè, àti gbogbo ohun tí ó ṣe, àti fún ẹ̀ṣẹ̀ tí ó ṣẹ̀, ṣé wọ́n kò kọ wọ́n sínú ìwé ìtàn àwọn ọba Júdà?

Ka pipe ipin 2 Ọba 21

Wo 2 Ọba 21:17 ni o tọ