2 Ọba 22:10 BMY

10 Nígbà náà Ṣáfánì akọ̀wé sọ fún ọba pé, “Hílíkíyà àlùfáà ti fún un ní ìwé kan.” Ṣáfánì kà lára rẹ̀ níwájú ọba.

Ka pipe ipin 2 Ọba 22

Wo 2 Ọba 22:10 ni o tọ