2 Ọba 22:16 BMY

16 ‘Èyí ni ohun tí Olúwa wí: Èmi yóò mú ibi wá sí ibí àti àwọn ènìyàn rẹ ní ìbámu pẹ̀lú gbogbo ohun tí a kọ sínú ìwé tí ọba Júdà ti kà.

Ka pipe ipin 2 Ọba 22

Wo 2 Ọba 22:16 ni o tọ