2 Ọba 22:18 BMY

18 Sọ fún ọba Júdà tí ó rán yín láti bèrè lọ́wọ́ Olúwa, ‘Èyí ni ohun tí Olúwa Ọlọ́run Ísírẹ́lì wí nípa ọ̀rọ̀ wọ̀n-ọn-nì tí ìwọ ti gbọ́.

Ka pipe ipin 2 Ọba 22

Wo 2 Ọba 22:18 ni o tọ