2 Ọba 22:6 BMY

6 Àwọn gbẹ́nà-gbẹ́nà, àwọn ọ̀mọ̀lé àti àwọn akọ́lé. Bákan náà ni wọ́n ra igi àti òkúta ọlọ́ṣọ̀ọ́ láti fi tún tẹ́ḿpìlì ṣe.

Ka pipe ipin 2 Ọba 22

Wo 2 Ọba 22:6 ni o tọ