2 Ọba 22:8 BMY

8 Hílíkíyà olórí àlùfáà sọ fún Ṣáfánì akọ̀wé pé, “Èmi rí ìwé òfin nílé Olúwa.” Ó fi fún Ṣáfánì, ẹni tí ó kà á.

Ka pipe ipin 2 Ọba 22

Wo 2 Ọba 22:8 ni o tọ