2 Ọba 23:3 BMY

3 Ọba sì dúró lẹ́bà òpó, ó sì sọ májẹ̀mú di titun níwájú Olúwa láti tẹ̀lé Olúwa àti láti pa òfin rẹ̀ mọ́, ìlànà àti òfin pẹ̀lú gbogbo ọkàn rẹ̀ àti gbogbo ẹ̀mí rẹ̀, àti láti ṣe ìwádìí àwọn ọ̀rọ̀ májẹ̀mú tí a kọ sínú ìwé yìí. Nígbà náà, gbogbo àwọn ènìyàn sì ṣèlérí fúnra wọn sí májẹ̀mú náà.

Ka pipe ipin 2 Ọba 23

Wo 2 Ọba 23:3 ni o tọ