2 Ọba 24:5 BMY

5 Ní ti ìyókù iṣẹ́ ìjọba Jéhóíákímù, àti gbogbo nǹkan tí ó ṣe, ṣé wọn kò kọ wọ́n sínú ìwé ìtàn ọba Júdà?

Ka pipe ipin 2 Ọba 24

Wo 2 Ọba 24:5 ni o tọ