2 Ọba 24:7 BMY

7 Ọba Éjíbítì kò sì tún jáde ní ìlú rẹ̀ mọ́, nítorí ọba Bábílónì ti gba gbogbo agbégbé rẹ̀ láti odò Éjíbítì lọ sí odò Éúférátè.

Ka pipe ipin 2 Ọba 24

Wo 2 Ọba 24:7 ni o tọ