2 Ọba 25:14 BMY

14 Wọ́n sì kóo lọ pẹ̀lú àwo ìkòkò ọkọ́, àlùmágàjí fìtílà, síbí àti gbogbo ohun èló idẹ tí wọ́n lò nílé tí wọ́n fi sisẹ́.

Ka pipe ipin 2 Ọba 25

Wo 2 Ọba 25:14 ni o tọ