2 Ọba 25:3 BMY

3 Nígbà tí ó di ọjọ́ kẹsàn-án oṣù kẹrin, iyàn tí mú ní ìlú tí ó jẹ́ wí pé kò sí oúnjẹ fún àwọn ènìyàn láti jẹ.

Ka pipe ipin 2 Ọba 25

Wo 2 Ọba 25:3 ni o tọ