2 Ọba 25:8 BMY

8 Ní ọjọ́ kèje ní oṣù karùn ún, ní ọdún ìkọkàndínlógún ti Nebukadinésárì ọba Bábílónì, Nebukadinéṣárì olórí ẹ̀sọ́ ti ọba ìjòyè ọba Bábílónì wá sí Jérúsálẹ́mù

Ka pipe ipin 2 Ọba 25

Wo 2 Ọba 25:8 ni o tọ