2 Ọba 3:20 BMY

20 Ní òwúrọ̀ ọjọ́ kejì, ní àsìkò ẹbọ ọrẹ, níbẹ̀ ni omí ṣàn láti ọ̀kánkán Édómù! Ilé náà sì kún pẹ̀lú omi.

Ka pipe ipin 2 Ọba 3

Wo 2 Ọba 3:20 ni o tọ