2 Ọba 4:12 BMY

12 Ó sì wí fún ìránṣẹ́ rẹ̀ Géhásì pé, “Pe ará Ṣúnémù.” Bẹ́ẹ̀ ni ó sì pè é wá, ó sì dúró níwájú rẹ̀.

Ka pipe ipin 2 Ọba 4

Wo 2 Ọba 4:12 ni o tọ