2 Ọba 4:19 BMY

19 “Orí mi!, Orí mi!” Ó wí fún baba rẹ̀.Baba rẹ̀ sọ fún ìránṣẹ́, “Gbé e lọ sọ́dọ̀ ìyá rẹ̀.”

Ka pipe ipin 2 Ọba 4

Wo 2 Ọba 4:19 ni o tọ